2 Kọ́ríńtì 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Kì í ṣe pé a jẹ́ ọ̀gá lórí ìgbàgbọ́ yín,+ àmọ́ a jọ ń ṣiṣẹ́ kí ẹ lè máa láyọ̀, torí ìgbàgbọ́ yín ló mú kí ẹ dúró. 1 Pétérù 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 ẹ má ṣe jẹ ọ̀gá lórí àwọn tó jẹ́ ogún Ọlọ́run,+ àmọ́ kí ẹ jẹ́ àpẹẹrẹ fún agbo.+
24 Kì í ṣe pé a jẹ́ ọ̀gá lórí ìgbàgbọ́ yín,+ àmọ́ a jọ ń ṣiṣẹ́ kí ẹ lè máa láyọ̀, torí ìgbàgbọ́ yín ló mú kí ẹ dúró.