Mátíù 18:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ bí ọmọ kékeré yìí ni ẹni tó tóbi jù lọ nínú Ìjọba ọ̀run;+ Mátíù 23:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àmọ́ kí ẹni tó tóbi jù lọ láàárín yín jẹ́ ìránṣẹ́ yín.+ Máàkù 10:43, 44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 43 Kò gbọ́dọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàárín yín; àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di ẹni ńlá láàárín yín gbọ́dọ̀ jẹ́ ìránṣẹ́ yín,+ 44 ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láàárín yín gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹrú gbogbo yín. Lúùkù 22:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́ kò yẹ kí ẹ̀yin ṣe bẹ́ẹ̀.+ Kí ẹni tó tóbi jù láàárín yín dà bí ẹni tó kéré jù,+ kí ẹni tó jẹ́ aṣáájú sì dà bí ẹni tó ń ṣe ìránṣẹ́.
4 Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ bí ọmọ kékeré yìí ni ẹni tó tóbi jù lọ nínú Ìjọba ọ̀run;+
43 Kò gbọ́dọ̀ rí bẹ́ẹ̀ láàárín yín; àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ di ẹni ńlá láàárín yín gbọ́dọ̀ jẹ́ ìránṣẹ́ yín,+ 44 ẹnikẹ́ni tó bá sì fẹ́ jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ láàárín yín gbọ́dọ̀ jẹ́ ẹrú gbogbo yín.
26 Àmọ́ kò yẹ kí ẹ̀yin ṣe bẹ́ẹ̀.+ Kí ẹni tó tóbi jù láàárín yín dà bí ẹni tó kéré jù,+ kí ẹni tó jẹ́ aṣáájú sì dà bí ẹni tó ń ṣe ìránṣẹ́.