Lúùkù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó wá sọ àpèjúwe yìí, ó ní: “Ọkùnrin kan gbin igi ọ̀pọ̀tọ́ sínú ọgbà àjàrà rẹ̀, ó sì wá síbẹ̀, ó ń wá èso lórí rẹ̀, àmọ́ kò rí ìkankan.+
6 Ó wá sọ àpèjúwe yìí, ó ní: “Ọkùnrin kan gbin igi ọ̀pọ̀tọ́ sínú ọgbà àjàrà rẹ̀, ó sì wá síbẹ̀, ó ń wá èso lórí rẹ̀, àmọ́ kò rí ìkankan.+