-
Máàkù 11:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó wá tajú kán rí igi ọ̀pọ̀tọ́ kan tó ní ewé lọ́ọ̀ọ́kán, ó sì lọ wò ó bóyá òun máa rí nǹkan kan lórí rẹ̀. Àmọ́, nígbà tó débẹ̀, kò rí nǹkan kan àfi ewé, torí kì í ṣe àsìkò èso ọ̀pọ̀tọ́.
-