Lúùkù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kódà, àwọn agbowó orí wá, kí wọ́n lè ṣèrìbọmi,+ wọ́n sì sọ fún un pé: “Olùkọ́, kí ni ká ṣe?” Lúùkù 7:29, 30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 (Nígbà tí gbogbo èèyàn àti àwọn agbowó orí gbọ́ èyí, wọ́n kéde pé olódodo ni Ọlọ́run, torí Jòhánù ti ṣe ìrìbọmi fún wọn.+ 30 Àmọ́ àwọn Farisí àti àwọn tó mọ Òfin dunjú kò ka ìmọ̀ràn* tí Ọlọ́run fún wọn sí,+ torí pé kò tíì ṣe ìrìbọmi fún wọn.)
29 (Nígbà tí gbogbo èèyàn àti àwọn agbowó orí gbọ́ èyí, wọ́n kéde pé olódodo ni Ọlọ́run, torí Jòhánù ti ṣe ìrìbọmi fún wọn.+ 30 Àmọ́ àwọn Farisí àti àwọn tó mọ Òfin dunjú kò ka ìmọ̀ràn* tí Ọlọ́run fún wọn sí,+ torí pé kò tíì ṣe ìrìbọmi fún wọn.)