Róòmù 13:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìfẹ́ kì í ṣiṣẹ́ ibi sí ọmọnìkejì ẹni;+ torí náà, ìfẹ́ ni àkójá òfin.+ Gálátíà 5:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí a ti mú gbogbo Òfin ṣẹ nínú* àṣẹ kan ṣoṣo, tó sọ pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+
14 Nítorí a ti mú gbogbo Òfin ṣẹ nínú* àṣẹ kan ṣoṣo, tó sọ pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+