ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 19:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 “‘O ò gbọ́dọ̀ gbẹ̀san+ tàbí kí o di ọmọ àwọn èèyàn rẹ sínú, o sì gbọ́dọ̀ nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.+ Èmi ni Jèhófà.

  • Mátíù 7:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 “Torí náà, gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.+ Ní tòótọ́, ohun tí Òfin àti àwọn Wòlíì túmọ̀ sí nìyí.+

  • Mátíù 22:39
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 39 Ìkejì tó dà bíi rẹ̀ nìyí: ‘Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.’+

  • Róòmù 13:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ẹ má jẹ ẹnikẹ́ni ní gbèsè ohunkóhun, àmọ́ kí ẹ máa nífẹ̀ẹ́ ara yín;+ nítorí ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ̀ ti mú òfin ṣẹ.+ 9 Nítorí àkójọ òfin tó sọ pé, “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè,+ o ò gbọ́dọ̀ pààyàn,+ o ò gbọ́dọ̀ jalè,+ o ò gbọ́dọ̀ ṣojúkòkòrò”+ àti àṣẹ míì tó bá wà, ni a kó pọ̀ sínú ọ̀rọ̀ yìí, pé: “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ.”+

  • Jémíìsì 2:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Tí ẹ bá ń mú ọba òfin ṣẹ bó ṣe wà nínú ìwé mímọ́ pé, “Kí o nífẹ̀ẹ́ ọmọnìkejì rẹ bí ara rẹ,”+ ẹ̀ ń ṣe dáadáa gan-an ni.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́