Ẹ́kísódù 20:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ilé ọmọnìkejì rẹ wọ̀ ọ́ lójú. Ojú rẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ ìyàwó ọmọnìkejì rẹ+ tàbí ẹrúkùnrin rẹ̀ tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ tàbí akọ màlúù rẹ̀ tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ tàbí ohunkóhun tó jẹ́ ti ọmọnìkejì rẹ.”+
17 “O ò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ilé ọmọnìkejì rẹ wọ̀ ọ́ lójú. Ojú rẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ ìyàwó ọmọnìkejì rẹ+ tàbí ẹrúkùnrin rẹ̀ tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀ tàbí akọ màlúù rẹ̀ tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ tàbí ohunkóhun tó jẹ́ ti ọmọnìkejì rẹ.”+