Mátíù 6:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Torí náà, ẹ máa gbàdúrà lọ́nà yìí:+ “‘Baba wa tí ń bẹ ní ọ̀run, kí orúkọ+ rẹ di mímọ́.*+