ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 16:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Àwọn èèyàn máa lé yín kúrò nínú sínágọ́gù.+ Kódà, wákàtí náà ń bọ̀, nígbà tí ẹnikẹ́ni tó bá pa yín+ máa rò pé ṣe lòun ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún Ọlọ́run.

  • Ìṣe 7:59
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 59 Bí wọ́n ṣe ń sọ òkúta lu Sítéfánù, ó bẹ̀bẹ̀ pé: “Jésù Olúwa, gba ẹ̀mí mi.”

  • Ìṣe 12:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ní àkókò yẹn, Ọba Hẹ́rọ́dù bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni sí àwọn kan nínú ìjọ.+ 2 Ó fi idà+ pa Jémíìsì arákùnrin Jòhánù.+

  • Ìfihàn 6:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 A fún ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní aṣọ funfun kan,+ a sì sọ fún wọn pé kí wọ́n sinmi fúngbà díẹ̀ sí i, títí iye àwọn ẹrú bíi tiwọn àti àwọn arákùnrin wọn tí wọ́n máa tó pa bí wọ́n ṣe pa àwọn náà fi máa pé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́