ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 24:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 “Nígbà náà, àwọn èèyàn máa fà yín lé ìpọ́njú lọ́wọ́,+ wọ́n á sì pa yín,+ gbogbo orílẹ̀-èdè sì máa kórìíra yín nítorí orúkọ mi.+

  • Ìṣe 8:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Sọ́ọ̀lù, ní tirẹ̀, fọwọ́ sí bí wọ́n ṣe pa Sítéfánù.+

      Ní ọjọ́ yẹn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni tó lágbára sí ìjọ tó wà ní Jerúsálẹ́mù; gbogbo àwọn ọmọ ẹ̀yìn tú ká lọ sí gbogbo agbègbè Jùdíà àti Samáríà, àwọn àpọ́sítélì nìkan ni kò tú ká.+

  • Ìṣe 12:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ní àkókò yẹn, Ọba Hẹ́rọ́dù bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni sí àwọn kan nínú ìjọ.+ 2 Ó fi idà+ pa Jémíìsì arákùnrin Jòhánù.+

  • Ìṣe 26:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Bí mo ṣe ń fìyà jẹ wọ́n léraléra ní gbogbo sínágọ́gù, mo fipá mú wọn láti fi ìgbàgbọ́ wọn sílẹ̀; torí pé inú wọn ń bí mi gidigidi, mo bá a débi pé mo ṣe inúnibíni sí wọn ní àwọn ìlú tó wà lẹ́yìn òde pàápàá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́