Máàkù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kódà, ẹran ara kankan ò ní là á já, àfi tí Jèhófà* bá dín àwọn ọjọ́ náà kù. Àmọ́ nítorí àwọn àyànfẹ́ tó yàn, ó dín àwọn ọjọ́ náà kù.+
20 Kódà, ẹran ara kankan ò ní là á já, àfi tí Jèhófà* bá dín àwọn ọjọ́ náà kù. Àmọ́ nítorí àwọn àyànfẹ́ tó yàn, ó dín àwọn ọjọ́ náà kù.+