Mátíù 24:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Kódà, ẹran ara kankan ò ní là á já, àfi tí a bá dín àwọn ọjọ́ yẹn kù; àmọ́ nítorí àwọn àyànfẹ́, a máa dín àwọn ọjọ́ yẹn kù.+
22 Kódà, ẹran ara kankan ò ní là á já, àfi tí a bá dín àwọn ọjọ́ yẹn kù; àmọ́ nítorí àwọn àyànfẹ́, a máa dín àwọn ọjọ́ yẹn kù.+