ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Máàkù 13:21-23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 “Bákan náà, tí ẹnikẹ́ni bá sọ fún yín nígbà yẹn pé, ‘Ẹ wò ó! Kristi wà níbí’ tàbí ‘Ẹ wò ó! Òun nìyẹn,’ ẹ má gbà á gbọ́.+ 22 Torí àwọn èké Kristi àti àwọn wòlíì èké máa dìde,+ wọ́n sì máa ṣe àwọn iṣẹ́ àmì àti àwọn iṣẹ́ ìyanu láti kó àwọn àyànfẹ́ pàápàá ṣìnà, tó bá ṣeé ṣe. 23 Torí náà, ẹ ṣọ́ra.+ Mo ti sọ gbogbo nǹkan fún yín ṣáájú.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́