-
Lúùkù 21:25, 26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 “Bákan náà, àwọn àmì máa wà nínú oòrùn, òṣùpá àti àwọn ìràwọ̀,+ ìdààmú sì máa bá àwọn orílẹ̀-èdè ní ayé, wọn ò ní mọ ọ̀nà àbáyọ torí ariwo omi òkun àti bó ṣe ń ru gùdù. 26 Àwọn èèyàn máa kú sára nítorí ìbẹ̀rù àti àwọn ohun tí wọ́n ń retí pé ó máa ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ ayé tí à ń gbé, torí a máa mi àwọn agbára ọ̀run.
-