29 “Ẹsẹ̀kẹsẹ̀ lẹ́yìn ìpọ́njú àwọn ọjọ́ yẹn, oòrùn máa ṣókùnkùn,+ òṣùpá ò sì ní mọ́lẹ̀, àwọn ìràwọ̀ máa já bọ́ láti ọ̀run, a sì máa mi àwọn agbára ọ̀run.+
24 “Àmọ́ nígbà yẹn, lẹ́yìn ìpọ́njú yẹn, oòrùn máa ṣókùnkùn, òṣùpá ò sì ní mọ́lẹ̀,+25 àwọn ìràwọ̀ á máa já bọ́ láti ọ̀run, a sì máa mi àwọn agbára tó wà ní ọ̀run.