Lúùkù 12:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 “Ẹ múra, kí ẹ sì wà ní sẹpẹ́,*+ kí ẹ jẹ́ kí àwọn fìtílà yín máa jó,+ Fílípì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+
15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+