Mátíù 25:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “A lè fi Ìjọba ọ̀run wé wúńdíá mẹ́wàá tí wọ́n mú fìtílà wọn,+ tí wọ́n sì jáde lọ pàdé ọkọ ìyàwó.+ Fílípì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+
15 kí ẹ lè jẹ́ aláìlẹ́bi àti ọlọ́wọ́ mímọ́, ọmọ Ọlọ́run+ tí kò ní àbààwọ́n láàárín ìran onímàgòmágó àti oníwà ìbàjẹ́,+ láàárín àwọn tí ẹ ti ń tàn bí ìmọ́lẹ̀ nínú ayé,+