Lúùkù 19:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “Nígbà tó pa dà dé lẹ́yìn tó gba agbára láti jọba,* ó pe àwọn ẹrú tó fún ní owó* náà, kó lè mọ èrè tí wọ́n jẹ nínú òwò tí wọ́n ṣe.+
15 “Nígbà tó pa dà dé lẹ́yìn tó gba agbára láti jọba,* ó pe àwọn ẹrú tó fún ní owó* náà, kó lè mọ èrè tí wọ́n jẹ nínú òwò tí wọ́n ṣe.+