Mátíù 25:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “Lẹ́yìn tó ti pẹ́ gan-an, ọ̀gá àwọn ẹrú yẹn dé, wọ́n sì jọ yanjú ọ̀rọ̀ owó.+