ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 12:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “‘Kí ẹ máa rántí ọjọ́ yìí, kí ẹ sì máa ṣe ayẹyẹ rẹ̀, kó jẹ́ àjọyọ̀ sí Jèhófà jálẹ̀ àwọn ìran yín. Ẹ máa pa àjọyọ̀ náà mọ́, ó ti di òfin fún yín títí láé.

  • Máàkù 14:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó ku ọjọ́ méjì+ kí wọ́n ṣe Ìrékọjá+ àti Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin sì ń wá bí wọ́n ṣe máa fi ọgbọ́n àrékérekè* mú un,* kí wọ́n sì pa á;+ 2 torí wọ́n sọ pé: “Kì í ṣe nígbà àjọyọ̀; torí ariwo lè sọ látọ̀dọ̀ àwọn èèyàn.”

  • Lúùkù 22:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú, tí wọ́n ń pè ní Ìrékọjá,+ ti ń sún mọ́lé.+ 2 Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin sì ń wá ọ̀nà tó máa dáa gan-an láti rẹ́yìn rẹ̀,+ torí wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn.+

  • Jòhánù 13:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Torí pé Jésù ti mọ̀ ṣáájú àjọyọ̀ Ìrékọjá pé wákàtí òun ti tó+ láti kúrò ní ayé yìí lọ sọ́dọ̀ Baba,+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn tirẹ̀ tó wà ní ayé, ó sì nífẹ̀ẹ́ wọn dé òpin.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́