ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 21:45, 46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Nígbà tí àwọn olórí àlùfáà àti àwọn Farisí gbọ́ àwọn àpèjúwe rẹ̀, wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń bá wí.+ 46 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé wọ́n fẹ́ mú un,* wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èrò, torí wòlíì ni àwọn èèyàn náà kà á sí.+

  • Mátíù 26:3-5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà wá kóra jọ sínú àgbàlá àlùfáà àgbà, tí wọ́n ń pè ní Káyáfà,+ 4 wọ́n sì gbìmọ̀ pọ̀+ kí wọ́n lè fi ọgbọ́n àrékérekè* mú* Jésù, kí wọ́n sì pa á. 5 Àmọ́ wọ́n sọ pé: “Kì í ṣe nígbà àjọyọ̀, kí ariwo má bàa sọ láàárín àwọn èèyàn.”

  • Máàkù 14:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó ku ọjọ́ méjì+ kí wọ́n ṣe Ìrékọjá+ àti Àjọyọ̀ Búrẹ́dì Aláìwú.+ Àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin sì ń wá bí wọ́n ṣe máa fi ọgbọ́n àrékérekè* mú un,* kí wọ́n sì pa á;+ 2 torí wọ́n sọ pé: “Kì í ṣe nígbà àjọyọ̀; torí ariwo lè sọ látọ̀dọ̀ àwọn èèyàn.”

  • Lúùkù 20:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Àwọn akọ̀wé òfin àti àwọn olórí àlùfáà wá ń wá bí ọwọ́ wọn ṣe máa tẹ̀ ẹ́ ní wákàtí yẹn gangan, àmọ́ wọ́n ń bẹ̀rù àwọn èèyàn, torí wọ́n mọ̀ pé àwọn ló ń fi àpèjúwe yìí bá wí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́