-
Ẹ́kísódù 21:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Tí akọ màlúù náà bá kan ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin kan, ẹni tó ni ín yóò san ọgbọ̀n (30) ṣékélì* fún ọ̀gá ẹrú yẹn, wọ́n á sì sọ akọ màlúù náà lókùúta pa.
-