ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 26:14, 15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Lẹ́yìn náà, ọ̀kan nínú àwọn Méjìlá náà, tí wọ́n ń pè ní Júdásì Ìsìkáríọ́tù,+ lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà,+ 15 ó sì sọ pé: “Kí lẹ máa fún mi, kí n lè fà á lé yín lọ́wọ́?”+ Wọ́n bá a ṣe àdéhùn ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà.+

  • Mátíù 27:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ìgbà yẹn ni ohun tí a sọ nípasẹ̀ wòlíì Jeremáyà ṣẹ pé: “Wọ́n kó ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà, iye owó tí wọ́n dá lé ọkùnrin náà, ẹni tí àwọn kan lára àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá iye owó kan lé,

  • Máàkù 14:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Júdásì Ìsìkáríọ́tù, ọ̀kan nínú àwọn Méjìlá náà, lọ sọ́dọ̀ àwọn olórí àlùfáà láti fà á lé wọn lọ́wọ́.+ 11 Inú wọn dùn nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n sì ṣèlérí pé àwọn máa fún un ní owó fàdákà.+ Torí náà, ó bẹ̀rẹ̀ sí í wá ìgbà tó máa dáa jù láti fà á lé wọn lọ́wọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́