Diutarónómì 27:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)
25 “‘Ègún ni fún ẹni tó bá gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ẹni tí kò mọwọ́ mẹsẹ̀.’*+ (Kí gbogbo èèyàn sì sọ pé, ‘Àmín!’)