Sekaráyà 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ìwọ idà, dìde sí olùṣọ́ àgùntàn mi,+Sí ọkùnrin tó jẹ́ ọ̀rẹ́ mi. Kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ kí agbo* sì tú ká;+Èmi yóò sì yí ọwọ́ mi pa dà sí àwọn tí kò já mọ́ nǹkan kan.” Máàkù 14:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Gbogbo wọn fi í sílẹ̀, wọ́n sì sá lọ.+ Jòhánù 16:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹ wò ó! Wákàtí náà ń bọ̀, ní tòótọ́, ó ti dé, nígbà tí wọ́n máa tú ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ká sí ilé rẹ̀, ẹ sì máa fi èmi nìkan sílẹ̀.+ Àmọ́ mi ò dá wà, torí pé Baba wà pẹ̀lú mi.+
7 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ìwọ idà, dìde sí olùṣọ́ àgùntàn mi,+Sí ọkùnrin tó jẹ́ ọ̀rẹ́ mi. Kọ lu olùṣọ́ àgùntàn,+ kí agbo* sì tú ká;+Èmi yóò sì yí ọwọ́ mi pa dà sí àwọn tí kò já mọ́ nǹkan kan.”
32 Ẹ wò ó! Wákàtí náà ń bọ̀, ní tòótọ́, ó ti dé, nígbà tí wọ́n máa tú ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ká sí ilé rẹ̀, ẹ sì máa fi èmi nìkan sílẹ̀.+ Àmọ́ mi ò dá wà, torí pé Baba wà pẹ̀lú mi.+