Àìsáyà 53:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+ Ìṣe 8:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Àyọkà Ìwé Mímọ́ tó ń kà nìyí: “Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á, bí ọ̀dọ́ àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò la ẹnu rẹ̀.+
7 Wọ́n ni ín lára,+ ó sì jẹ́ kí wọ́n fìyà jẹ òun,+Àmọ́ kò la ẹnu rẹ̀. Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,+Bí abo àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀,Kò sì la ẹnu rẹ̀.+
32 Àyọkà Ìwé Mímọ́ tó ń kà nìyí: “Wọ́n mú un wá bí àgùntàn sí ibi tí wọ́n ti fẹ́ pa á, bí ọ̀dọ́ àgùntàn tó dákẹ́ níwájú àwọn tó ń rẹ́ irun rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni kò la ẹnu rẹ̀.+