Máàkù 15:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Nígbà tí ọ̀gágun tó dúró ní ọ̀ọ́kán rẹ̀ rí i pé ó ti gbẹ́mìí mì, pẹ̀lú àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ yìí, ó sọ pé: “Ó dájú pé Ọmọ Ọlọ́run ni ọkùnrin yìí.”+
39 Nígbà tí ọ̀gágun tó dúró ní ọ̀ọ́kán rẹ̀ rí i pé ó ti gbẹ́mìí mì, pẹ̀lú àwọn nǹkan tó ṣẹlẹ̀ yìí, ó sọ pé: “Ó dájú pé Ọmọ Ọlọ́run ni ọkùnrin yìí.”+