ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 27:54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 54 Àmọ́ nígbà tí ọ̀gágun àti àwọn tó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ tí wọ́n ń ṣọ́ Jésù rí bí ilẹ̀ ṣe mì tìtì àtàwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀, ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi, wọ́n sì sọ pé: “Ó dájú pé Ọmọ Ọlọ́run nìyí.”+

  • Lúùkù 23:47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Nígbà tí ọ̀gágun náà rí ohun tó ṣẹlẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í yin Ọlọ́run lógo, ó ní: “Ní tòótọ́, olódodo ni ọkùnrin yìí.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́