-
Lúùkù 24:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àwọn obìnrin náà ni Màríà Magidalénì, Jòánà àti Màríà ìyá Jémíìsì. Bákan náà, àwọn obìnrin yòókù tó wà pẹ̀lú wọn ń sọ àwọn nǹkan yìí fún àwọn àpọ́sítélì.
-