ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 28:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 28 Lẹ́yìn Sábáàtì, nígbà tí ilẹ̀ ń mọ́ bọ̀ ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, Màríà Magidalénì àti Màríà kejì wá wo sàréè náà.+

  • Máàkù 16:1, 2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Torí náà, nígbà tí Sábáàtì+ ti kọjá, Màríà Magidalénì, Màríà+ ìyá Jémíìsì àti Sàlómẹ̀ ra àwọn èròjà tó ń ta sánsán kí wọ́n lè wá fi pa á lára.+ 2 Ní àárọ̀ kùtù ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, nígbà tí oòrùn ti yọ, wọ́n wá síbi ibojì* náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́