Lúùkù 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àmọ́ ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, wọ́n wá síbi ibojì* náà ní àárọ̀ kùtù, wọ́n gbé èròjà tó ń ta sánsán tí wọ́n ṣe dání.+ Jòhánù 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, Màríà Magidalénì wá síbi ibojì* náà ní àárọ̀ kùtù,+ nígbà tí ilẹ̀ ò tíì mọ́, ó sì rí i pé wọ́n ti gbé òkúta náà kúrò níbi ibojì* náà.+
24 Àmọ́ ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, wọ́n wá síbi ibojì* náà ní àárọ̀ kùtù, wọ́n gbé èròjà tó ń ta sánsán tí wọ́n ṣe dání.+
20 Ní ọjọ́ kìíní ọ̀sẹ̀, Màríà Magidalénì wá síbi ibojì* náà ní àárọ̀ kùtù,+ nígbà tí ilẹ̀ ò tíì mọ́, ó sì rí i pé wọ́n ti gbé òkúta náà kúrò níbi ibojì* náà.+