ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 23:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Má fi wàhálà pa ara rẹ torí kí o lè kó ọrọ̀ jọ.+

      Fara balẹ̀ kí o sì lo òye.*

       5 Nígbà tí o bá bojú wò ó, kò ní sí níbẹ̀,+

      Torí ó dájú pé ó máa hu ìyẹ́ bí ẹyẹ idì, á sì fò lọ sójú ọ̀run.+

  • Máàkù 10:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Lẹ́yìn tí Jésù wò yí ká, ó sọ fún àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ pé: “Ẹ wo bó ṣe máa ṣòro tó fún àwọn olówó láti wọ Ìjọba Ọlọ́run!”+

  • Lúùkù 18:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Jésù wò ó, ó sì sọ pé: “Ẹ wo bó ṣe máa ṣòro tó fún àwọn olówó láti rí ọ̀nà wọ Ìjọba Ọlọ́run!+

  • 1 Tímótì 6:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àmọ́ àwọn tó pinnu pé àwọn fẹ́ di ọlọ́rọ̀ máa ń kó sínú ìdẹwò àti ìdẹkùn+ àti ọ̀pọ̀ ìfẹ́ ọkàn tí kò bọ́gbọ́n mu, tó sì lè pani lára, èyí tó ń mú kí àwọn èèyàn pa run kí wọ́n sì ṣègbé.+

  • 2 Tímótì 4:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìdí ni pé Démà+ ti pa mí tì torí ó nífẹ̀ẹ́ ètò àwọn nǹkan yìí,* ó sì ti lọ sí Tẹsalóníkà, Kírẹ́sẹ́ńsì ti lọ sí Gálátíà, Títù sì ti lọ sí Damatíà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́