-
Mátíù 10:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Torí náà, ẹ má bẹ̀rù wọn, torí kò sí nǹkan tí a bò mọ́lẹ̀ tí a ò ní tú síta, kò sì sí ohun tó jẹ́ àṣírí tí a ò ní mọ̀.+