-
Máàkù 4:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Torí kò sí nǹkan tí a fi pa mọ́ tí a kò ní tú síta; kò sí ohun tí a rọra tọ́jú tí kò ní hàn sí gbangba.+
-
-
Lúùkù 8:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Torí kò sí nǹkan tí a fi pa mọ́ tí kò ní hàn kedere, kò sí ohun tí a rọra tọ́jú tí a ò ṣì ní mọ̀, tí kò sì ní hàn sí gbangba.+
-