-
Jòhánù 6:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ṣebí Jésù ọmọ Jósẹ́fù nìyí, tí a mọ bàbá àti ìyá rẹ̀?+ Kí ló dé tó wá sọ pé, ‘Mo sọ̀ kalẹ̀ wá láti ọ̀run’?”
-