Lúùkù 4:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Lẹ́yìn náà, ó lọ sí Násárẹ́tì,+ níbi tí wọ́n ti tọ́ ọ dàgbà, ó wọnú sínágọ́gù,+ ó sì dìde dúró láti kàwé, bó ṣe máa ń ṣe ní ọjọ́ Sábáàtì. 17 Torí náà, wọ́n fún un ní àkájọ ìwé wòlíì Àìsáyà, ó ṣí àkájọ ìwé náà, ó sì rí ibi tí wọ́n kọ ọ́ sí pé:
16 Lẹ́yìn náà, ó lọ sí Násárẹ́tì,+ níbi tí wọ́n ti tọ́ ọ dàgbà, ó wọnú sínágọ́gù,+ ó sì dìde dúró láti kàwé, bó ṣe máa ń ṣe ní ọjọ́ Sábáàtì. 17 Torí náà, wọ́n fún un ní àkájọ ìwé wòlíì Àìsáyà, ó ṣí àkájọ ìwé náà, ó sì rí ibi tí wọ́n kọ ọ́ sí pé: