Mátíù 2:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ó wá lọ ń gbé ní ìlú kan tí à ń pè ní Násárẹ́tì,+ kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì lè ṣẹ, pé: “A máa pè é ní ará Násárẹ́tì.”*+
23 Ó wá lọ ń gbé ní ìlú kan tí à ń pè ní Násárẹ́tì,+ kí ohun tí a sọ nípasẹ̀ àwọn wòlíì lè ṣẹ, pé: “A máa pè é ní ará Násárẹ́tì.”*+