Róòmù 13:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ fún gbogbo èèyàn ní ohun tí ó tọ́ sí wọn: ẹni tó béèrè owó orí, ẹ fún un ní owó orí;+ ẹni tó béèrè ìṣákọ́lẹ̀,* ẹ fún un ní ìṣákọ́lẹ̀; ẹni tí ìbẹ̀rù yẹ, ẹ bẹ̀rù rẹ̀ bó ṣe yẹ;+ ẹni tí ọlá yẹ, ẹ bọlá fún un bó ṣe yẹ.+ Títù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo, 1 Pétérù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ
7 Ẹ fún gbogbo èèyàn ní ohun tí ó tọ́ sí wọn: ẹni tó béèrè owó orí, ẹ fún un ní owó orí;+ ẹni tó béèrè ìṣákọ́lẹ̀,* ẹ fún un ní ìṣákọ́lẹ̀; ẹni tí ìbẹ̀rù yẹ, ẹ bẹ̀rù rẹ̀ bó ṣe yẹ;+ ẹni tí ọlá yẹ, ẹ bọlá fún un bó ṣe yẹ.+
3 Máa rán wọn létí pé kí wọ́n máa tẹrí ba fún ìjọba àti àwọn aláṣẹ, kí wọ́n máa ṣègbọràn sí wọn,+ kí wọ́n sì múra tán láti máa ṣe iṣẹ́ rere gbogbo,
13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ