-
Ẹ́kísódù 3:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Áńgẹ́lì Jèhófà fara hàn án nínú ọwọ́ iná tó ń jó láàárín igi ẹlẹ́gùn-ún kan.+ Bó ṣe ń wò ó, ó rí i pé iná ń jó lára igi ẹlẹ́gùn-ún náà, síbẹ̀ igi náà ò jóná.
-
-
Mátíù 22:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ní ti àjíǹde àwọn òkú, ṣé ẹ ò tíì ka ohun tí Ọlọ́run sọ fún yín ni, pé:
-