Mátíù 26:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Lóòótọ́, Ọmọ èèyàn ń lọ, bí a ṣe kọ ọ́ nípa rẹ̀, àmọ́ ọkùnrin tí a tipasẹ̀ rẹ̀ fi Ọmọ èèyàn léni lọ́wọ́+ gbé!+ Ì bá sàn fún ọkùnrin náà ká ní wọn ò bí i.”+
24 Lóòótọ́, Ọmọ èèyàn ń lọ, bí a ṣe kọ ọ́ nípa rẹ̀, àmọ́ ọkùnrin tí a tipasẹ̀ rẹ̀ fi Ọmọ èèyàn léni lọ́wọ́+ gbé!+ Ì bá sàn fún ọkùnrin náà ká ní wọn ò bí i.”+