-
Lúùkù 22:39-41Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Nígbà tó kúrò níbẹ̀, ó lọ sí Òkè Ólífì bó ṣe máa ń ṣe, àwọn ọmọ ẹ̀yìn náà sì tẹ̀ lé e.+ 40 Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀, ó sọ fún wọn pé: “Ẹ máa gbàdúrà, kí ẹ má bàa kó sínú ìdẹwò.”+ 41 Ó wá kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó lọ sí ìwọ̀n ibi tí òkúta lè dé tí wọ́n bá jù ú látọ̀dọ̀ wọn, ó kúnlẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbàdúrà,
-