Mátíù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Gbogbo nǹkan yìí ni Jésù fi àpèjúwe sọ fún àwọn èrò náà. Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe,+
34 Gbogbo nǹkan yìí ni Jésù fi àpèjúwe sọ fún àwọn èrò náà. Ní tòótọ́, kì í bá wọn sọ̀rọ̀ láìlo àpèjúwe,+