Ẹ́kísódù 23:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “O ò gbọ́dọ̀ tan ìròyìn èké kálẹ̀.*+ Má ṣe lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú ẹni burúkú láti jẹ́rìí èké.+ Ẹ́kísódù 23:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Má ṣe lọ́wọ́ sí ẹ̀sùn èké,* má sì pa aláìṣẹ̀ àti olódodo, torí mi ò ní pe ẹni burúkú ní olódodo.*+ Léfítíkù 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jalè,+ ẹ ò gbọ́dọ̀ tanni jẹ,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ hùwà àìṣòótọ́ sí ara yín.
7 “Má ṣe lọ́wọ́ sí ẹ̀sùn èké,* má sì pa aláìṣẹ̀ àti olódodo, torí mi ò ní pe ẹni burúkú ní olódodo.*+