-
Mátíù 3:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ní tèmi, mò ń fi omi batisí yín torí pé ẹ ronú pìwà dà,+ àmọ́ ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi lágbára jù mí lọ, ẹni tí mi ò tó bọ́ bàtà rẹ̀.+ Ẹni yẹn máa fi ẹ̀mí mímọ́+ àti iná+ batisí yín. 12 Ṣọ́bìrì tó fi ń fẹ́ ọkà wà lọ́wọ́ rẹ̀, ó sì máa gbá ibi ìpakà rẹ̀ mọ́ tónítóní, ó máa kó àlìkámà* rẹ̀ jọ sínú ilé ìkẹ́rùsí, àmọ́ ó máa fi iná+ tí kò ṣeé pa sun ìyàngbò.”*
-