Sáàmù 45:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ lo rẹwà jù lọ nínú àwọn ọmọ èèyàn. Ọ̀rọ̀ rere ń jáde lẹ́nu rẹ.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi bù kún ọ títí láé.+ Àìsáyà 50:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+
2 Ìwọ lo rẹwà jù lọ nínú àwọn ọmọ èèyàn. Ọ̀rọ̀ rere ń jáde lẹ́nu rẹ.+ Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi bù kún ọ títí láé.+
4 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti fún mi ní ahọ́n àwọn tí a kọ́,*+Kí n lè mọ bó ṣe yẹ kí n fi ọ̀rọ̀ tó yẹ* dá ẹni tó ti rẹ̀ lóhùn.*+ Ó ń jí mi ní àràárọ̀;Ó ń jí etí mi kí n lè fetí sílẹ̀ bí àwọn tí a kọ́.+