Àìsáyà 40:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+ Málákì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé: “Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi, á sì tún ọ̀nà ṣe* dè mí.+ Lójijì, Olúwa tòótọ́, ẹni tí ẹ̀ ń wá yóò wá sí tẹ́ńpìlì rẹ̀;+ ìránṣẹ́ májẹ̀mú yóò sì wá, ẹni tí inú yín dùn sí. Wò ó! Ó dájú pé ó máa wá.
3 Ohùn ẹnì kan ń ké nínú aginjù pé: “Ẹ tún ọ̀nà Jèhófà ṣe!*+ Ẹ la ọ̀nà tó tọ́ + gba inú aṣálẹ̀ fún Ọlọ́run wa.+
3 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ pé: “Wò ó! Màá rán ìránṣẹ́ mi, á sì tún ọ̀nà ṣe* dè mí.+ Lójijì, Olúwa tòótọ́, ẹni tí ẹ̀ ń wá yóò wá sí tẹ́ńpìlì rẹ̀;+ ìránṣẹ́ májẹ̀mú yóò sì wá, ẹni tí inú yín dùn sí. Wò ó! Ó dájú pé ó máa wá.