Mátíù 4:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tó kúrò níbẹ̀, ó rí àwọn méjì míì tí wọ́n jẹ́ tẹ̀gbọ́n-tàbúrò, Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀.+ Inú ọkọ̀ ojú omi ni wọ́n wà pẹ̀lú Sébédè bàbá wọn, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe, ó sì pè wọ́n.+ Máàkù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Lẹ́yìn tó lọ síwájú díẹ̀ sí i, ó rí Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀ nínú ọkọ̀ ojú omi wọn, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe,+
21 Nígbà tó kúrò níbẹ̀, ó rí àwọn méjì míì tí wọ́n jẹ́ tẹ̀gbọ́n-tàbúrò, Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀.+ Inú ọkọ̀ ojú omi ni wọ́n wà pẹ̀lú Sébédè bàbá wọn, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe, ó sì pè wọ́n.+
19 Lẹ́yìn tó lọ síwájú díẹ̀ sí i, ó rí Jémíìsì ọmọ Sébédè àti Jòhánù arákùnrin rẹ̀ nínú ọkọ̀ ojú omi wọn, wọ́n ń tún àwọ̀n wọn ṣe,+