ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 24:5-9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 “Kí o mú ìyẹ̀fun tó kúnná, kí o fi ṣe búrẹ́dì méjìlá (12) tó rí bí òrùka. Ìyẹ̀fun tó jẹ́ ìdá méjì nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n eéfà* ni kí o fi ṣe búrẹ́dì kọ̀ọ̀kan. 6 Kí o tò wọ́n ní ìpele méjì, mẹ́fà ní ìpele kan,+ lórí tábìlì tí wọ́n fi ògidì wúrà ṣe, èyí tó wà níwájú Jèhófà.+ 7 Kí o fi ògidì oje igi tùràrí sórí ìpele kọ̀ọ̀kan, yóò sì jẹ́ búrẹ́dì ọrẹ ìṣàpẹẹrẹ*+ tó jẹ́ ọrẹ àfinásun sí Jèhófà. 8 Kó máa tò ó síwájú Jèhófà nígbà gbogbo+ ní ọjọ́ Sábáàtì kọ̀ọ̀kan. Májẹ̀mú tí mo bá àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dá ni, ó sì máa wà títí lọ. 9 Yóò di ti Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀,+ wọ́n á sì jẹ ẹ́ ní ibi mímọ́,+ torí ó jẹ́ ohun mímọ́ jù lọ fún un látinú àwọn ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, ìlànà tó máa wà títí lọ ni.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́