Ìṣe 7:59, 60 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 59 Bí wọ́n ṣe ń sọ òkúta lu Sítéfánù, ó bẹ̀bẹ̀ pé: “Jésù Olúwa, gba ẹ̀mí mi.” 60 Lẹ́yìn náà, ó kúnlẹ̀, ó sì fi ohùn líle ké jáde pé: “Jèhófà,* má ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn lọ́rùn.”+ Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó sùn nínú ikú. Róòmù 12:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ máa súre fún àwọn tó ń ṣe inúnibíni;+ ẹ máa súre, ẹ má sì máa ṣépè.+
59 Bí wọ́n ṣe ń sọ òkúta lu Sítéfánù, ó bẹ̀bẹ̀ pé: “Jésù Olúwa, gba ẹ̀mí mi.” 60 Lẹ́yìn náà, ó kúnlẹ̀, ó sì fi ohùn líle ké jáde pé: “Jèhófà,* má ka ẹ̀ṣẹ̀ yìí sí wọn lọ́rùn.”+ Lẹ́yìn tó sọ èyí, ó sùn nínú ikú.